YORUBA RCCG SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUALEKÓ KĘRÌNDÍNLÓGÚN: OJÓ KEJÌDÍNLÓGÚN, OSU KEJİLÁ ODÚN 2022 –
AKORI: İDARÍ ÀTI İTÓNI ÀTÒKÈWÁ (APÁ KÍNNI)
ÀDÚRÀ İBÈRÈ: Baba, jé kí èmí mi wà ní isopo
pèlú rę nígbà gbogbo.
OTHER MANUALS
- RCCG LOWER JUNIOR ZEAL AGE 4-5 TEACHER’S MANUAL 18TH OF DECEMBER 2022 LESSON SIXTEEN (16)
- RCCG JUNIOR ZEAL AGE 13-19 TEACHER’S MANUAL SUNDAY 18TH OF DECEMBER 2022 LESSON SIXTEEN (16)
- RCCG JUNIOR ZEAL AGE 9-12 TEACHER’S MANUAL SUNDAY 18TH OF DECEMBER 2022 LESSON SIXTEEN (16)
- RCCG JUNIOR ZEAL AGE 13-19 STUDENTS’ MANUAL SUNDAY 18TH OF DECEMBER 2022 LESSON 16
- RCCG YAYA SUNDAY SCHOOL STUDENT’S MANUAL LESSON SIXTEEN (16) SUNDAY 18TH OF DECEMBER 2022
- RCCG LOWER JUNIOR ZEAL AGE 6-8 TEACHER’S MANUAL SUNDAY 18TH OF DECEMBER 2022 LESSON SIXTEEN (16
- RCCG YAYA SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUAL LESSON SIXTEEN (16) SUNDAY 18TH OF DECEMBER 2022
- RCCG SUNDAY SCHOOL STUDENT’S MANUAL LESSON (16) 18TH DECEMBER 2022
- YORUBA RCCG SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUALEKÓ KĘRÌNDÍNLÓGÚN: OJÓ KEJÌDÍNLÓGÚN, OSU KEJİLÁ ODÚN 2022
- RCCG SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUAL LESSON SIXTEEN 18TH OF DECEMBER 2022
BÍBÉLİ KÍKÀ: Orin Dafidi 29:3-9.
3. Ohùn Oluwa mbẹ lori omi pupọ̀: Ọlọrun ogo nsán ãrá: Oluwa mbẹ lori omi pupọ̀.
5m4. Ohùn Oluwa li agbara; ohùn Oluwa ni ọlánla. Ohùn Oluwa nfà igi kedari ya; lõtọ, 5.Oluwa nfà igi kedari Lebanoni ya.
6. O mu wọn fò pẹlu bi ọmọ-malu; Lebanoni on Sirioni bi ọmọ agbanrere.
7. Ohùn Oluwa nyà ọwọ iná,
8. Ohùn Oluwa nmì aginju; Oluwa nmì aginju Kadeṣi.
9. Ohùn Oluwa li o nmu abo agbọnrin bi, o si fi igbo didi hàn: ati ninu tempili rẹ̀ li olukuluku nsọ̀rọ ogo rẹ̀.
ESÈ ÀKÓSÓRÍ: Èmi yóò fi esè rẹ lé
ònà, èmi ó sì kòọ lí ònà tí iwo ó rìn, èmi ó máa fi ojú mi tộợ Orin Dafidi 37:8.
İFÁÀRÁ: ldarí àtòkèwa jé láti gba idarí nípa Olurun. Kí Olórun máa tóni jé kókóró pàtàki kan fún àwọn kristięni. O jé nà kan şoşo láti lè mú ifé Olórun şę nínú gbogbo àwon igbésè ti ipinnu wa. (2Àwon oba 3:11). Nítorí náà a nílò láti kó nípa àwon ònà èyítí Qlórun ń gbà látid àti pèlú tó àwọn èniyàn rè.Síwájú síi ní àkókò yií, idarí àti itóni Emí mímó jé ohun kòşeémáàní.
İLÉPA ỆKO: Láti kó àwọn akékòó ní àwọn onà tí èniyàn lè gbà láti ní idárí àtòkèwá, àti bí a şe lè mo ó.
ÈRÒNGBÀ ÈKỘ: Ní òpin èkó yií, àwọn akékòó ní láti le:
a. S’àlàyé ohun tí idarí àti itóni àtòkèwá jé.
b. Dárúkọ onírúurú onà fún idarí àti itóni àtòkèwá.
d. Sọ bí wón şe lè mỳ bí wón bá ní idarí àti itóni àtòkèwá.
ÈTÒ KÍKÓNI: Láti ní imúsę àwọn orò òkè wònyí, kí olùkó:
a. Fún àwọn akékòó láàyè láti ka ęsè àkósórí, ka Bibeli kikà, dásí iforòwér), şe işé yàrá ikàwé şíşe àti işé àmúrelé.
b. Fún igbákeji, olùkó ní ánfààni láti şe àbójútó yàrá, ikékòó fi máàki fún àwọn tí wón wá àti işé àmúrelé.
d. Kó àwọn ilànà èkó, şe àkójop), ikáàdí, yànnàná èkó àti pèlú fún wọn ni işé àmúrelé.
ÀTÚNYỆWÒ BÍBÉLİ KÍKÀ: Orin Dafidi 29:3-9.
Onísáàmù nínú ibi kíkà yìí fi ara balè mú jáde bí igbe ayé ęni iwà bí Qlórun ș ní láti ri pèlú àwon àbájáde irúfé rè. Nínú iyànjú yìí, Ó wi pé:
i. Nígbàti iwo bá gbékèlé Olúwa àti pèlú şe rere, iwo yóò sì máa gbé ní ilè náà kí o sì máa hùwà òtító -ęse 3.
ii. Tí o bá ń şe inú dídùn sí Olúwa, oun ó si – esę 4.
iii. Tí o bá fi ònà rẹ lé Olúwa lówó—ęsę 5.
İv. —–ęsę 6.
v. Tí iwo bá simi–ęsę 7.
İLÀNÀ ÈKÓ
İLÀNÀ ÈKỘ 1: ÀWỌN ÒNÀ FÚN İDARÍ ÀTI İTÓNI ÀTÒKÈWÁ
O şe pàtàki láti mỳ pé Qlórun nínú olánlá rè lè gbà onírúurú àwọn ònà láti tó àti darí àwon wonnì tí wón fĩ ìgbékèlé won sínú rę. Díę lára won nì iwònyí:
A. Nípa òrò Qlórun (1Sam.3:21, Heb.1:1-2).
B. Nípasè olůjérií ti èmí (Rom.8:14, 16).
Olùjèrí ti èmí lè wá gégé bí àláfíà Qlórun tí ó kojá gbogbo òye (Filp. 4:6-7).
D. Nípasè ohun èmí Eyí tayọ jjérii nikan,ó jé gbígbó.
i. Gbígbó yìí lè jé ti inútí ó túmò sí pé kò sÍ ęlòmíràn ní itòsí rę tí ó túmộ sí wípé kò ęlòmírànní itòsí rẹ tí ó gbó ọ. Bibeli pèé ní”ohùn kélé tí n sorộ” gégé bí ohun jéjé tín sorò (1Awon oba 19:12).
ii. Nígbà mìíràn ohùn náà máa jáde wá laárín èrò àwọn eni iwà bí olórun (lşe Apo. 10:19)
iii. Ohun ti èmí náà tún lè jé ti òde nínú işèlè bàyí iwo yóò Wò yíká bi eni pé o gbọ ohùn tàbí eni pe elòmíràn ń gbọ ohùn tí ìwo náà gbọ(1 Sam 3:3-5, Işe Apo 9:3-5).
E. Nípasè àwọn ìfihàn, àlá, iran, ìmisí (Joęli 2:28).
i. Àlá lè wa láti inú àwon èrò okàn rẹ (Oniw.5:3) tàbí èşů (àwọn àlá tin ba ni lérù tàbí láti odò Olórun imỳ àyà tin tóni sónà tàbí işípayá (Jobu 33:14-17) Àlá máa sèlè nígbà tí èniyàn bá sùn wọra(lòsán tàbí lóru)
ii. İran lè wá nígbà tí èniyàn bá wà lójúfò kí ó sì rí ohun kan bí eni pé ó dúró tàbí àwòrán tín rìn (Dan 2:19).
iii. imísí da gégé bí wíwà ní agbede-méji àlá àti iran nígbà tí yóò dàbí eni pé gbogbo òye ti ara kò şişé mó ní àkókò náà. (Işe Apo 10:10-11).
Ę. Nípasệ àwọn işèlệ kan tí a fi àyè gba láti wáyé (Owe 24:30-34, Jer.18:1-6) Olórun lè mú ọ tàbí kí òun fún ọní itóni igbé ayé nípasè işèlè kan láti fi ònà hàn ọ kedere.
F. Nípasè àwon ohùn isotélè tàbí ifidánilójú (Hos.12:10).Şůgbón àwo onígbàgbọ ní láti kíyèsára nípa gbígbé igbé ayé won lé isotélè (1 Joh.4:1).
G. Nípasè onírúurú ònà tí ó bá wu Olórun (Hos. 12:10).
IŞÉ ŞÍŞE NÍ KÍLÁÀSI KÍNNÍ: Kí àwon akékòó şe àjopín èyíkèyí irírí ibásòrò pèlú olórun tí won tiní pèlú yàrá ikékòó.
İLÀNÀ ÈKÓ 2: MÍMộ ìDARÍ ÀTI İTÓNI
ÀTÒKÈWÁ
A. Emí mímó ni óní ojúşe itóni àti olùgbani níyànjú, tí ó sì ń tó wa ní ònà tí ó yę fún wa láti tò àti pèlú şe àfihàn òtító Olórun (Lk 12:12).
B. Okan pàtàki lára àwọn ònà láti mọ nígbà tí Emí mímó bá ń tóni jé láti bá òrò Olórun dàpo.
i. Bíbéli jé orísun ogbón tí ó ga julo nípa bí a şe lè gbé igbé ayé wa. (2Tim.3:16) àwọn onígbàgbó si ní láti wá inú iwé mímo dáradára (Joh.5:39) şe àşàrò lórí ręşe àşàrò lórí rę (0.D. 1:2).
ii. İdà émí ni òrỳ náà jé (Efe 6:17) Emí yóò si lòó láti fi báwa sòrò (Jn 16:12-14) láti şe àfihàn ifé Olórun fún ayé tí a nílò wá. Öun yóò tún mú iwé mímó tí a nílò wá sí okàn wa nígbà tí a nílò rè jùlo (Jn 14:26).
D. A gbodò máa dán àwọn ohun náà tí ń wá sí okàn wà èyítíó lòdi sí iwé mímó Wò rę ni wípé, Emí mímó kì yóò tìwá láti şe ohunkóhun tí lòdi orò Olórun (1Kọr.14:33). Tí ó bá tako Bíbéli, Ở túmò sí pé kií şe Emí mímó àti pé kí á yęra fún-un.
İ. Ó kún şe pàtàki fún wa láti wa nínú àdúrà lóòrè-kóòrè pèlú Baba (1Tẹs 5:17).
ii. Kií şe pé èyí ń şi okàn àti Ệmí wa payá sí idarí Emí mímó nikan şùgbón ó tún fún Emí mímó náà ní ànfààní láti sòrò nítorí wa. (Rom 8:26-27).
IŞÉ ŞÍŞE NÍ KÍLÁÀSI KEJİ: Kí àwon akékòó jíròrò pò síwájú síi lórí bí a şe lè mọ ìdarí àti itóni àtòkèwá.
İSONÍSÓKÍ: Níwòn igbà tí ó şe pàtàki fún àwon onígbágbó láti ní itóni Olórun mímó ònà láti tó wọn àti bí wọn yòò şe mọ ìdarí rè pèlú şe pàtàki.
İKÁDIÍ: TÍ iwo kò bá ní itóni àti ìdarí Olórun, ìwo yóò máa rìn iri àti pèlú sọnù nínú aginjù ayé. Jé kí Olórun máa tóọ.
IGBÉLÉWÒN: Kí olùkó pe àwon akékòó láti ş’àlàyé òye won nípa idarí àti itóni àtòkèwá.
ÀDÚRÀ İPARÍ: Baba, jé kí Emí mímó máa darí áti pèlú tómi nígbà gbogbo ní orúko Jésù.
ISÉ ÀSETILÉWÁ: Dárúko àwon ewu márùn-ún ti kíko etí dídi sí itóni àtòkèwá. (Máàki Méwàá).