YORUBA RCCG SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUAL EKO KỌKÀNDÍNLÓGUN: QJÓ KẸJO, OSU KÍNNÍ, ODÚN 2023 – AKORI: BU QLÁ FÚN OLÓRUN
ÀDÚRÀ İBÈRÈ: Baba, kó mi láti fé àti láti bu
olá fún ọ síi.
BÍBÉLİ KÍKÀ: 1 Samuęli 2:29-30.
ALL MANUALS TODAY
- RCCG YAYA SUNDAY SCHOOL STUDENT’S MANUAL LESSON NINETEEN (19) DATE: SUNDAY 8TH JANUARY 2023
- RCCG LOWER JUNIOR ZEAL FOR 2022/2023 AGE 4-12 TEACHER’S MANUAL SUNDAY 8TH OF JANUARY 2023 LESSON NINETEEN (19)
- RCCG JUNIOR ZEAL FOR 2022/2023 AGE 13-19 TEENS’ MANUAL SUNDAY 8TH OF JANUARY LESSON NINETEEN (19)
- RCCG SUNDAY SCHOOL STUDENT’S MANUAL LESSON: NINETEEN (19) DATE: SUNDAY 8TH JANUARY 20230
- RCCG YAYA SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUAL LESSON NINETEEN (19) DATE: SUNDAY 8TH JANUARY 2023
- RCCG SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUAL LESSON: NINETEEN (19) DATE: SUNDAY 8TH JANUARY 2023
- YORUBA RCCG SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUAL EKO KỌKÀNDÍNLÓGUN: QJÓ KẸJO, OSU KÍNNÍ, ODÚN 2023 – AKORI: BU QLÁ FÚN OLÓRUN
29. Eṣe ti ẹnyin fi tapa si ẹbọ ati ọrẹ mi, ti mo pa li aṣẹ ni ibujoko mi: iwọ si bu ọla fun awọn ọmọ rẹ jù mi lọ, ti ẹ si fi gbogbo ãyo ẹbọ Israeli awọn enia mi mu ara nyin sanra?
30. Nitorina Oluwa Ọlọrun Israeli wipe, Emi ti wi nitotọ pe, ile rẹ ati ile baba rẹ, yio ma rin niwaju mi titi: ṣugbọn nisisiyi Oluwa wipe, ki a má ri i; awọn ti o bu ọla fun mi li emi o bu ọla fun, ati awọn ti kò kà mi si li a o si ṣe alaikasi.
ESÈ ÀKÓSÓRÍ: “Omọ a máa bọlá fún, àti omọ ộdò fún Olúwa rè: hjệ bí èmi bá şebàbá, ọlá mi ha dà? Bí èmi bá sì şe Olúwa, èrù mi ha dà? Li Olúwa àwọn omọ-ogun wí fún nyín; Eyin àlúfà, tí ħgan Orúko mi. Ệyin sì wípé, Nínú kíni àwa fi kégan orúkọ rę? Malaki 1:6.
İFÁÀRÁ: Olá láti inú òrò Hébérů ‘tipharah’ túmò sí iyi, èyę tàbi ibòwò ńlá. Láti bu olá fún èniyàn ni mímó ríri irúfé ęni béệ tàbí bíbu iyi fúnra wa. Öşe pàtàkì láti kíyèsi pé gbogbo àşę àti olá ję ti Olórun nikan (1 Tim.1:17, Ifi.5:13) Ekó yií ń darí wa sí àwọn èrèdí àti bí a şe lè bu olá fún Olórun.
İLÉPA EKÓ: Láti kó àwọn akékòó ní bíbolá fún Olórun.
ÈRÒNGBÀ ÈKŐ: Léyin idắnilékòó yií, àwon akékòó yóò le:
a. Şàlàyé ohun tí bíbu olá fún Olórun túmò sí.
b. Sọ ìdí tí a fi níláti bọlá fún Qlórun.
d. Dárúkọ bí a şe gbódò bu ola fún Qlórun.
ÈTÒ KÍKNI: Láti mú kí èróńgbà òkè yií şe, kí olùko:
a. Fi ààyè sílę fún àwọn akékòó láti ka esè àkósóri, bíbéli kíkà, dá sí ijíròrò, şe işé şíşe ti
kíláási àti isé àşetiléwá wọn.
b. Fààyè sílè fún igbákeji olùkó láti mójútó kíláási, kí ó sì buwólùwé wíwásí ilé-èkó ojó isinmi àwon akékòó àti işé àşetiléwá.
d. Kó ilànà èkó méjèèji, şe àkópò, àkótán, igbéléwòn èkó àti fún akékỘó ní işé àşetiléwá.
ÀTÚNYỆWÒ BÍBÉLİ KÍKÀ: 1 Samuęli 2:29-30.
Ônkowé yií şe àkosílè àwon èsè Éli àti idíilé rè sí Olúwa àti àtúnbòtán fún àwọn İşesí yií.
A. İránsé Olórun so fún Eli pé kí ó
i. ————- esę 29a.
ii. ———— ęsę 29b.
iii. ———– esę 29d.
B. Nítórí àwọn èsè tí a kọsílè lókè wònyí, Olúwa Qlórun wí pé:
i. Lótitó mo wí pé ———— esę 30a.
ii. Şùgbón nísinsiyí ————- esę 30b.
iii. Fún ———– esę 30d.
QGBỘN İKỘNI: Qgbón ikóni ibéèrè àti idáhùn.
LÍLÒ ÀKÓKÒ: Kí olůkó pín àkokò sórí kíko ilànà èkó méjèji.
İLÀNÀ ÈKÓ 1: KÍNI ÈRÈDÍ TÍ A GBÓDO FI BU QLÁ FUN OLÓRUN
İdáhùn 1. Olórun ló yę láti gba gbogbo olá
(Ifihan 4:11).
a. kòi tîi sí rí tàbí tí yóò wà láéláé, enikéni ní ipò agbára yòówù tàbí ilúmoóká tí ó lè ní irú olá yìí (1 Tim 6:16).
b. Qlórun nikan ni aşèdá àti eni náà tí ó mú orun àti ayé dúró (Ifihan 14:7).
2. Gégé bí onígbàgbó, a bọlá fún Olộrun:
a. Fún irú ẹni tí ó jé (Isaiah 45:5-6).
b. Nítorí pé òun ni bàbá wa (Matt. 6:9b)
d. Nípa mímo ríri pé ẹbùn iyè ayérayé àti igbàlà ọkàn ọkàn wa wá nípasè Jésù Kristi àti Oun nikan (Jn 11:25, Işe Apo 4:12, 1Tim 2:5).
e. Fún işooré rè àti isé iyanu (0rin Daf. 107:15).
ę. Fún gbogbo èrè rè tí à ńjègbádùn (Orin Daf. 68:19).
Gbogbo onígbàgbó òdodo ní láti bu olá fún Olórun (Orin Daf. 134:1) nípasè imoríri àti ijéwó wa pé òun nikan ni Olórun (Eksodu 20:3).
IŞÉ ŞÍŞE NÍ KÍLÁÀSI KÍNNÍ: Kí àwọn akékòó dárúko àwọn èrèdí mìíràn tí wón fi gbódọ bu olá fún Olórun yàtò sí àwọn tí a ti ménubà wònyí.
İLÀNÀ ÈKÓ 2: BAWO NI A ŞE LÈ BU QLÀ
FÚN QLỘRUN?
İbéèrè 1: ÀWon onà wo ni a lè gbà bu ola
fun Olórun?
idáhùn: Onírúurú onà ló wà ti a lè gbà bu olá fún Olórun. Lára wọn ni a ménubà nísàlệ
wònyí:
i. Ań bọlá àti ijúbà fún un nípasè.
ii. Láti gbé Olórun ga, gégé bí eni àkókó nínú ayé wa, ni láti jowó ayé wa pátápátá fún ún àti kí fífi ohun tí a ní fún un.
iii. Åwon onígbàgbó níláti fi ohun iní wọn (eso akoko, idamęwa, orę, abbl) bu olá fún Olórun tokantokan (Owe 3:9-10).
iv. A gbódỳ bu olá fún lórun nípasę gbígbé igbe ayé iwà mímó nítorí pé mímó ni òun jé, ní àwòrán ara Rę ni o da wa (1 Pet.1:15-16)
İbéèrè 2: Njé èrè wà fún bíbu olá fún Olórun bí?
İdáhùn : Béèni, èrè ńlá ńbę fún bíbolá fún Ọlórun. Qlórun yóo:
i. Bú olá fún àwọn tí o bọla fún-un (1 Sam.2:30).
ii. Fi àkúnwosílè ibùkún fún àwọn tí o bu ola funun (Owe 3:9-10).
IŞÉ ŞÍŞE NÍ KÍLÁÀSI KEJİ: Kí àwon akékòó jíròrò bí won se le bu olá fún Qlórun láí fojú
ténbélú èniyàn.
İSONÍŞÓKÍ: A ní láti kọ bí a şe n bolá fún Qlórun nígbà gbogbo kí a ba le jègbádùn àkúnwosilę ibùkún rè.
İKÁDİİ: Olórun yę láti gba gbogbo olá, asì nílátifi fún un.
IGBÉLÈWÒN: Kí olükó sọ fún àwon akékòó láti şàlàyé ohun ti bíbu ola fún Olórun túmò sí àti bi a şe le bu ola fun-un.
ÀDÚRÀ ÌPARÍ: Baba, jé kí gbogbo ohun ti mo ję bu ola fún ọ nígbà gbogbo.
ISÉ ÀSETILÉWÁ: Dárúko ohun márùn ún pàtó tí iwo yóð şe láti fi bu ola fún Olórun lódún yìí (Máàki Méwàá).