YORUBA RCCG SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUAL ỌJỌ́ KỌKÀNDÍNLỌ́GBỌ̀N, OSU KÍNNÍ, ỌDÚN 2023.

YORUBA RCCG SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUAL ỌJỌ́ KỌKÀNDÍNLỌ́GBỌ̀N, OSU KÍNNÍ, ỌDÚN 2023. AKORI: ÀWẸ̀ GBÍGBÀ NÍNÚ BÍBÉLÌ ÀDÚRÀ ÌBẸ̀RẸ̀: Baba, rànmí lọ́wọ́ láti lóye nípa àgbékalẹ̀ bíbélì fún ááwẹ̀ gbígbà. ÌMỌ̀ ÀTẸ̀HÌNWÁ: Kí olùkọ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láyè láti ṣe àtúnyẹ̀wò ẹ̀kọ́ ti ọ̀sẹ̀ tó kọja. BÍBÉLÌ KÍKÀ: Daniẹli 10:2-3. …

Read More »