YORUBA RCCG SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUAL Ẹ̀KỌ́ KẸRÌNLÉLÓGÚN ỌJỌ́ KEJÌLÁ, OSU KEJI, ỌDÚN 2023. AKORI: ÈSO TI Ẹ̀MÍ MÍMỌ́ (APÁ KEJÌ) ÀDÚRÀ ÌBẸ̀RẸ̀: Baba, rànmílọ́wọ́ láti lóye bí mo ṣe lè so èso òdodo. ÌMỌ̀ ÀTẸ̀HÌNWÁ: Kí olùkọ́ ṣe àtúnyẹ̀wò ẹ̀kọ́ ti ọ̀sẹ̀ tó kọja. BÍBÉLÌ KÍKÀ: Galatia 5:16-18. 16. Njẹ mo …
Read More »